Ji Okan Mi Ba Orun Ji – Yoruba Hymn

Verse 1

Ji okan mi ba orun ji
Mura si ise oojo re
Ma se ilora ji kutu
K’o san gbese ebo oro

Verse 2

Ro gbogb’ ojo t’o fi sofo
Bere si rere se loni
Kiyes’ irin re laiye yi
K’ o si mura d’ojo nla ni

Verse 3

Gba ninu imole orun
Si tanmole na f’elomi
Je ki ogo Olorun re
Han n’nu iwa ati ise re

Verse 4

Ji gbon ‘ra nu, ‘wo okan mi
Yan ipo re larin Angel
Awon ti nwon nkorin iyin
Ni gbogbo oru s’ Oba wa

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *